Àwòránhùn ẹ̀fẹ̀ tí ó ń ṣàfihàn àwọn òṣìṣẹ́ àjọ EFCC tí àwọn ológun ń yẹ̀yẹ́ tàn káàkiri

Share

Àwòránhùn kan tí ó ń ṣàfihàn àwọn òṣìṣẹ́ Economic and Financial Crimes Commission (EFCC) tí wọ́n ń jà pẹ̀lú àwọn ọkùnrin méjì tí wọ́n wọ aṣọ ológun ti tàn káàkiri orí ayélujára.

Most Read

Recent Checks