#YorùbáFactCheck: Àwọn àhesọ irọ́ Ahmed Isah nípa abẹ́rẹ́ àjẹsára HPV tàn káàkiri Nigeria

Share

Àhesọ kan pé abẹ́rẹ́ àjẹsára Human Papillomavirus (HPV) léwu fún àwọn ọ̀dọ́mọbìnrin àti pé abẹ́rẹ́ náà wà láti ṣe àdínkù iye àwọn ènìyàn ní Nigeria ti tàn káàkiri gbogbo orílẹ̀ èdè yìí.

Most Read

Recent Checks