Yoruba Posts

Fact Guage:

Ilé-iṣẹ́ ìfọpo bentiró Dangote kò fi dọ́là ta epo si àwọn ọjà Nigeria

Àwòránhùn ètò àgbésáfẹ́fẹ́ kan láti ọwọ́ News Central TV tí ń tàn káàkiri orí ẹ̀rọ-ayélujára pẹ̀lú àhesọ pé ilé-iṣẹ́ ìfọpo Dangote sọ pé òun...

Simon Ekpa pín àwọn ayédèrú àwòrán ohun ìjà tí àwọnajìjàgbara Biafra gba padà lọ́wọ́ àwọn ọlọ́pàá Nigeria

Ajìjàgbara Biafra kan, Simon Ekpa, ti ṣe àgbéjáde àwọn àwòrán tí ó ń ṣàfihàn àwọn ohun ìjà ogun pẹ̀lú àhesọ pé àwọn ọmọ ogun...

Àwòránhùn àwọn ènìyàn tí wọ́n ń dìhànràn fún búrẹ́dì ní Ìlọrin kì í ṣe laipẹ́

Olùdíje nínú ẹgbẹ́ People's Democratic Party (PDP) fún Asojú ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin ní Ẹkùn Dekina/Bassa Fender fun àwọn ìdìbò gbogbogbò Nigeria ní ọdun 2023,...
00:05:47

Ìwádìí òótọ́ nípa ọ̀rọ̀ àwọn èèkàn òṣèlú Nigeria lásìkò àwọn Àdáṣe Ìdìbò Gómìnà ní ípínlẹ Imo, Kogi

Àwọn èèkàn òṣèlú kan pín àwọn ìròyìn èké síwájú, lásìkò àti lẹ́yìn àwọn àdáṣe ìdìbò tí wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ ṣe tán ni àwọn Ìpínlẹ̀ Bayelsa,...
00:02:30

Àwòránhùn ẹ̀fẹ̀ tí ó ń ṣàfihàn àwọn òṣìṣẹ́ àjọ EFCC tí àwọn ológun ń yẹ̀yẹ́ tàn káàkiri

Àwòránhùn kan tí ó ń ṣàfihàn àwọn òṣìṣẹ́ Economic and Financial Crimes Commission (EFCC) tí wọ́n ń jà pẹ̀lú àwọn ọkùnrin méjì tí wọ́n...
00:02:57

#YorùbáFactCheck: Àwọn àhesọ irọ́ Ahmed Isah nípa abẹ́rẹ́ àjẹsára HPV tàn káàkiri Nigeria

Àhesọ kan pé abẹ́rẹ́ àjẹsára Human Papillomavirus (HPV) léwu fún àwọn ọ̀dọ́mọbìnrin àti pé abẹ́rẹ́ náà wà láti ṣe àdínkù iye àwọn ènìyàn ní...

Most Read

Recent Checks